Description
These lesson notes cover the following topics for SS3 First and Second Term Yoruba:
FIRST TERM
OSE | AKORI EKO |
1 | EDE – Itesiwaju eko lori oro ise; Alaye lori orisii ati ilo re ninu gbolohun
ASA – Afiwe asa Isinku abinibi ati eto sinku ode oni. Ayipada to ti de ba Asa isinku abinibi tabi atohunrinwa LITIRESO – Agbeyewo iwe ti Ajo WAEC/NECO yan. Onkowe, itan ni soki ati awon amuye miiran |
2 | EDE – Itesiwaju eko lori isori gbolohun gege bi ihun won. Gbolohun eleyo oro ise, gbolohun olopo oro-ise, sise akojopo gbolohun eleyo oro-ise.
ASA – Eto ogunjije. Awon iran/orile ti o maa n jagun ni ile Yoruba laye atijo. Eto aabo ilu ati ipati awon obinrin n ko ninu eto ogun LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan |
3 | EDE – Itesiwaju lori ihun oro
Dida oro oruko ti asede mo yato si eyi ti a ko seda Itupale oro oruko eniyan, sise akojopo oro oruko ASA – Itesiwaju eko lori Egbe Awo Orisirisii egbe Awo ti o wa nile Yoruba Alaye kiku lori ipa ti awon egbe wonyii n ko ninu eto oselu LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan |
4 | EDE – Iba Isele (Aseranwo oro-ise)
i. Orisii iba isele to wa Asetan, Aterere, Aisetan abbl ii. Awon wunreni ti o toka iba isele ninu gbolohun ASA – Itesiwaju eko nipa igbagbo ati ero Yoruba nipa oso ati aje. Ero ati igbagbo awon eya miiran ni orile ede Naijiiria ati orile ede miiran nipa oso ati aje LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan |
5 | EDE – Itesiwaju lori Oro Agbaso
Yiyo oro enu oloro si oro agbaso, fifi eti si sise, kika ati jijabo iroyin ipade Yiya afo agba oro si afo-asafo ASA – Itesiwaju lori Eko ile ati imototo itoju ara, bi a se nkini, oro siso, onje jije ati awo fifo LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan |
6 | EDE – Itesiwaju lori oro aroko oniroyin, ijiroro kikun lori awon ori oro to je mo aroko oniroyin. Kiko ilapa ero
ASA – Itesiwaju eko lori ojuse eni ni awujo pataki ojuse eni ninu ile, laarin ebi, egbe, adugbo, abbl LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan |
7 | EDE – Iyato to wa laarin Oro Aponle ati Apola Aponle, alaye kikun. Oro Aponle ati Apola Aponle, titoka si ilo oro aponle ninu gbolohun, fifa oro aponle ati apola aponle yo ninu gbolohun tabi ipinro, sise alaye ise okookan won ninu gbolohun. Alopo mejeeji ninu gbolohun
ASA – Itesiwaju lori oran dida ati ijiya ti o to ipa ti awon agbefoba ati agbonfinro n ko ninu sise eto idajo fun arufin ati odaran, orisii eto idajo ati oan ti a o gba fi iya je odaran laye atijo ati ode oni LITIRESO – Ayewo finifini lori awon Asayn itandowe. Itandowe siso, itandowe kookan ni oloro geere titoba si oew ati asa to suyo ninu itan kookan, isowolo ede ninu itan to di owe kookan. |
8 | EDE – itesiwaju ninu aayan ogbufo. Ogbon ti a n ta fun aayan ogbufo lati ede geesi si ojulowo ede Yoruba. Fifoye itumo ayoka oloro geere to ta koko jut i ateyinwa lo lati inu ede geesi si ojulowo Yoruba ajumolo
ASA – Itesiwaju nipa igbagbo awon Yoruba si aseyin waye ati abami eda LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan |
9. | EDE – Itesiwaju Akaye Ayoka (orisirisi, agbeyewo orisirisi, akaye bii oloro geere, ewi, ere onitan, ati orisii ayoka danra wo
ASA – Itesiwaju lori eewo. Awon eewo ti aisan mu wa akojopo aisan ati eewo ti alaisan kookan ko gbodo deja, anfaani awon eewo fun awon alaisan LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan |
10 | EDE – Atunyewo awon isori oro-oruko, oro aropo oruko, oro ise, sise itupale gbolohun kekere si isori oro
ASA – Itesiwaju lori oruko ile Yoruba, oruko Amutorunwa, oruko abiso ati oriki inagije LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan |
11 | Atunyewo eko lori ise saa yii ninu ede, asa ati litireso |
12 | Akanse idanwo lori eko, ede, asa ati litireso |
SECOND TERM
OSE | AKORI EKO |
1 | EDE – Atunyewo eko kikun lori silebu ede Yoruba
ASA – Atunyewo eko lori Elegbejegbe, iro-si-iro LITIRESO – Agbeyweo asayan iwe ti ajo WAEC/NECO yan Onkowe, eda itan ati awon amuye inu itan yii |
2 | EDE – Atunyewo eko lori eko fonoloji ede Yoruba
B.A foniimu konsonanti, faweli, ohun, konsonanti aranmupe, asesilebu Eda foniimu, konsonanti ati faweli ASA – Agbeyewo awon orisa ile Yoruba Obatala, Orunmila/Ifa. Itan ni soki nipa awon Aworo Orisa LITIRESO – Itupale asayan iwe ajo WAEC/NECO yan |
3 | EDE – Atunyewo eko lori oro ayalo minu oro ayalo wo inu ede Yoruba
ASA – Atunyewo eko lori eko ebi ati iserun eni LITIRESO – Itupale asayan iwe ti ajo WAEC/NECO yan |
4 | EDE – Atunyewo kikun lori eko ihun oro ai iseda oro-oruko
ASA – Atunyewo kikun lori ede eto iselu abinibi ati ode-oni LITIRESO – Itupale asayan iwe ajo WAEC/NECO yan |
5 | EDE – Atunyewo eko lori isori oro; oro oruko, oro aropo oruko, aoro aropo afarajoruko, oro ise
ASA – Atunyewo eko lori oge sise, aso wiwo, itoju ara, ila kiko abbl. LITIRESO – Atunyewo eko lori alo apamo, apagbe ati itandowe abbl |
6 | EDE – Atunyewo eko lori isori ori apejuwe, oro aponle, oro asopo ati oro atokun
ASA – Atunyewo kikun lori asa igbeyawo ni ile Yoruba LITIRESO – Itupale Asayan iwe ti ajo WAEC/NECo yan |
To download Complete First to Second Term SS3 Yoruba Lesson Notes, scroll up and click on the “Order Now” button!
Reviews
There are no reviews yet.