Second Term JSS3 Yoruba Lesson Note
Pay with your ATM Card, USSD code or Bank Transfer to get immediate access to the download link page (download link will also be sent to your email address) for JSS3 Second Term Yoruba lesson note. Payments are securely handled by Paystack.
₦500.00

Description
This lesson note covers the following topics for JSS3 Second Term Yoruba:
SECOND TERM E-LEARNING NOTE.
ISÉ ; YORÙBÁ
KÍLÀÀSÌ ; J.S THREE
ÌLÀNÀ IS̩É̩́ KÍKÓ̩;
Ò̩SÈ̩ ORÍ- Ò̩RÒ̩
1[a] Èdè; Hìhun orisirisi awé̩- gbólóhùn pò̩ di odidi gbólóhùn
[b]Àsà; Àwo̩n àsà tó súyo̩ láti inú orin etíye̩rí àti dadakúàdà
[d]Lítírésò̩; Àkóónú orin etíyerí àti dadakúàdà
2[a]Èdè; Àròko̩ lé̩tàkíko̩ – àìgbè̩fè̩
[b]Àsà; Àwo̩n orìsà àti èèwò̩ tó súyo̩ nínú lítírésò̩ Yorùbá
[d]Lítírèsò̩; Ìfáàrà lórí àwò̩n lítírésò̩ alohùn tí a ń fi ò̩rò̩ wo̩n dá
wo̩n mo̩.
3[a]Èdè; Ìyàtò̩ tó wà láàrín àpólá àti awé̩- gbólóhùn Yorùbá
[b]Àsà; Ìtàn ìsè̩dálè̩ àgbáyé.
4[a]Èdè; Àròko̩ alálàyé 1: Ìtó̩nisónà àti àròso̩
[b]Àsà; Òwe Yorùbá
[d]Lítírésò̩; Oríkì orílè̩ – e̩lé̩rìn, olókùne̩sin abbl
5[a]Èdè; Àròko̩ alálàyé II
[b]Àsà; Àwo̩n àkànlò ò̩rò̩ Yorùbá
[d]Lítírésò̩; Kíka ìwé àpilè̩ko̩ tí ìjo̩ba yàn.
6[a]Èdè; Àkàyé 1- o̩ló̩rò̩ wuuru/ geere
[b]Àsà; Àwón imo̩lè̩/òrìsà tó súyo̩ nínú lítírés̩o̩
[d]Lítírésò̩; Kíka ìwé àpilè̩ko̩ tí ìjo̩ba yàn.
7[a]Èdè; Àkàyé II- Ewì
[b]Àsà; Àwón imo̩lè̩/òrìsà tó súyo̩ nínú lítírés̩o̩
[d]Lítírésò̩; Kíka ìwé àpilè̩ko̩ tí ìjo̩ba yàn.
8[a]Èdè; Àtúnyè̩wò àwo̩n è̩yán ò̩rò̩
[b]Àsà; Ìgbésè ìgbéyàwó ní ilè Yorùbá
[d]Lítírésò̩; Kíka ìwé àpilè̩ko̩ tí ìjo̩ba yàn.
9[a]Èdè; Àtúnyèwò àwo̩n ò̩rò̩ àpó̩nlé
[b]Àsà; Ìkómojáde ní ilè̩ Yorùbá
[d]Lítírés̩ò̩; Kíka ìwé àpilè̩ko̩ tí ìjo̩ba yàn.
10Àtúnyèwò isé sáà kíní
11Àtúnyèwò isé sáà kejì
12Àtúnyèwò isé̩ lori ìwé lítírésò̩ tí ìjo̩ba yàn
13Ìdánwo sáà kéjì