Description
This lesson note covers the following topics for SS2 Third Term Yoruba:
OSE | AKORI EKO |
1 | EDE – Atunyewo lori Aroko ajemo isipaya:
i. Ilana ero aroko ajemo isipaya ii. Akole, Ifaara, koko oro, agbalo gbdo iii. Alaye kikun lori eto ipin afo iv. Kiko aroko lori akole bii Omi, Iyan,Oja ati bee lo ASA – Atunyewo lori eko ile: i. Ibowofagba, ikini, bi o se ye ni gbogbo igba, suuru, otito sise, iforiti, igboran ati bee bee lo LITIRESO – Itupale asayan iwe ti ajo WAEC/NECO yan ti rgbe Akomolede fi owo si. |
2 | EDE – Atunyewo lori silebu ede Yoruba:
i. Oriki silebu ii. Silebu oni faweli kan (F) iii. Silebu alakanpo konsonanti ati faweli iv. Pipin oro si silebu ASA – Atunyewo ise abinibi: i. Ise agbe, gege bi ise abinibi gbogbo wa. Awon ohun elo ise agbe: Oko, Ada, ati bee bee lo ii. Ise agbede, ise alapata, ise akope ati ise gbenagbena ati bee bee lo LITIRESO – Itesiwaju lori atupale awon iwe Litireso: i. Awon eda itan ii. Ibudo itan |
3 | EDE – Atunyewo aroko onisorongbesi:
i. Alaye lori oro onisorongbesi ii. Kiko aroko onisorongbesi to dale isele awujo ASA – Ona ibanisoro: i. Lilo awon eya ara fun ibanisoro bii sise ni ni eekanna, ori gbongbon, oju sise, ara mimi, titenimole, imu yinyin ati iparoko. LITIRESO – Itupale iwe litireso: Ahunpo itan ati awon asa Yoruba to seyo ninu itan naa |
4 | EDE – Atunyewo ihun oro
i. Siseda oro rouko ii. Alaye lori awon oro oruko ti a ko seda sugbon ti won dabi eyi ti aseda bi ile, oba, omo, iay ati bee bee lo ASA – Itesiwaju eko lori ona ibanisoro: i. Ibanisoro ni aye ode oni bi iwe iroyin, telifonu, redio, foonu, foonu alagbekaa 1 meeli ati fasi (fax) LITIRESO – Sise atupale asayan iwe litireso: i. Awon ilo ede/Akanlo ede ii. Sise orinkinniwin won |
5 | EDE – Onka Yoruba:
i. Lati egbaa de oke meedogbon on (2,000 – 500,000) ASA – Awon orisa ile Yoruba: i. Ogun, Obatala, Esu ii. Awon ohun ti a fi n bo eon ati oriki okookan won LITIRESO – Kika iwe asayan ti ijoba yan |
6 | EDE – Onka Yoruba:
i. Lati oke meedogbon on de Aadota (500,000 – 1,000,000) ASA – Awon orisa ile Yoruba ati bi a se n bo won: i. Orunmila, Sango ii. Awon ohun ti a fi n bo won ati oriki okookan won LITIRESO – Kika sayan iwe litereso Yoruba ti ajo WAEC/NECO yan |
7 | EDE – Atunyewo awon eya ara ifo:
i. Lilo awon eya ara ifo ii. Alaye lori afipe asunsi ati afipe akanmole ASA – Awon orisa ati bi a se n bo won: i. Awon orisa miiran ni agbegbe awon akeeko ii. Ipo orisa ni ile Yourba iii. Pataki orisa lawujo Yoruba LITIRESO – Kika iwe litireso Yoruba ti ijoba yan |
8 | EDE – Atunyewo awon iro ninu ede Yoruba:
i. Iro faweli, iro konsonanti ati iro ohun ASA – Ero ati igbagbo awon Yoruba lori Oso ati Aje: i. Ise ti awon aje n se ninu isegun ati iwosan LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan |
9. | EDE – Atunyewo apejuwe iro konsonanti ati iro faweli:
i. Yiya ate faweli ati konsonanti ii. Sise apejuwe awon iro konsonanti ati faweli leyo kookan ASA – Ero ati igbagbo Yoruba lori akudaaya ati abami eda: i. Akudaaya ati abami eda bii Egbere, Iwin, Alujonu, Ebora ati bee bee lo LITIRESO – Kikai we litireso ti ijoba yan |
10 | EDE – Atunyewo eko lori ami ohun:
i. Kiko ami ohun Yoruba meteeta ii. Alaye lori ise ti ami ohun n se ninu ede Yoruba ASA – Igbagbo Yoruba nipa ori tabi eleeda: LITIRESO – Kika iwe litireso Yoruba ti ijoba yan fun saa yi |
11 & 12 | Atunyewo lori gbogbo ise saa yii ati idanwo ipari saa keta lori Ede, Asa ati Litireso ede Yoruba |
Need Third Term SS2 Yoruba Lesson Note? Scroll up and use the “Order Now” Button to download a copy today!
Reviews
There are no reviews yet.