Description
This lesson note covers the following topics for SS2 Second Term Yoruba:
OSE | AKORI EKO |
1 | EDE – Aroko (Leta gbefe)
i. Awon eto ati ilana leta gbefe ii. Adiresi ikini, deeti, koko oro, asokagba ati bee bee lo ASA – Isinku ni ile Yoruba I i. Orisirisi bii iku se n pani apeere, aisan, ijamba lorisirisi, afomowofe ati bee bee lo ii. Itufo ati itoju oku ni ile Yoruba iii. Ibanikedun ati sise oku agba LITIRESO – Asayan iwe litireso ti ajo WAEC/NECO yan ti egbe akomolede ipinle Eko fi owo si |
2 | EDE – Aayan ogbufo
i. Titumo ayolo ewi ni ede geesi si ede Yoruba ii. Awon offin to ro mo aayan ogbufo ASA – Isinku ni ile Yoruba II i. Orisirisi oku ati bi a se n sin won (a) Oku omode (b) Oku obinrin (d) Awon oku abami ii. Oku riro ati etutu oku sise bi ti elegun ba ku, won gbodo se etutu fun un ki eegun si jade lojo naa LITIRESO – Itupale lori iwe Litireso ti ajo WAEC/NECO yan fun SS2 i. Awon eda itan ii. Ibudo itan |
3 | EDE – Aayan ogbufo oloro wuuru:
i. Titumo eyo oto gbolohun ede geesi si ojulowo ede Yoruba ii. Titumo ayolo ipin afo lati ede geesi si ede Yoruba ASA – Eto ogun jije I i. Itumo ogun ati ohun ti an je logun ii. Iyato laarin ogun iya ati baba iii. Ona ti a n gba pin ogun ni ile Yoruba iv. Awon ti o ni eto si ogun pinpin v. Aleebu to rom o ogun pinpin LITIRESO – Itupale iwe litireso: Ahunpo itan ati asa Yoruba to suyo ninu itan naa |
4 | EDE – Aroko (leta aigbagbefe)
i. Igbese leta aigbagbefe ii. Adiresi, deeti, ikini, akole, koko oro, ikaadi, oruko ati ifowosi ASA – Eto ogun pinpin II Ipa ti ofin ijoba n ko lori ogun laye ode oni LITIRESO – Sise itupale asayan iwe litireso: i. Awon ilo ede lakanlo ede ii. Sise orinkinniwin won |
5 | EDE – Iparoje ati isunki:
i. Pipa iroje ibi ti ipaje yii ti le waye apola oruko apola ise ati awon ihun miiran ASA – Eto idajo laye atijo: i. Ona ti a fi n se idajo laye atijo beere lati odo oba, baale ati ijoye ii. Ipa ti emese / ilari n ko ninu eto idajo LITIRESO – Kika iwe asayan ti ajo WAEC/NECO yan |
6 | EDE – Aranmo:
i. Itumo aranmo ii. Orisii aranmo iii. Ofin to ro mo aranmo ASA – Eto idajo lode oni: i. Idajo lode oni ni ile ejo orisirisi, ile ejo ibile, ile ejo giga, ile ejo kotemilorun, ile ejo togajulo igbimo, eleti gbaroye ati beebee lo ii. Ipa ti olopaa ati woda n ko ninu idajo ode oni iii. Ise agbejoro ninu idajo odeoni iv. Eto yiyanju aawo lori redio ati telifison LITIRESO – Kika sayan iwe litereso Yoruba ti ijoba yan |
7 | EDE – Oro agbaso:
i. Afo asafo ii. Afo agba oro iii. Awon wunren ti maa n lo ninu oro agbaso ASA – Aroko pipa: i. Orisirisi awon n kan ti a fin paroko ati itumo won ii. Idi/anfani ti a fin paroko ni ile Yoruba LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan |
8 | EDE – Oro/gbolohun onipoona:
i. Itumo poona ii. Akojopo awon oro onipoona iii. Alaye lori itumo oro ati gbolohun onipoona ASA – Eewo ni ile Yoruba: i. Kini eewo/orisi eewo ii. Orisirisi eewo ati itumo okankan won iii. Ki ni o maa n sele ti eniyan ba deja eewo ati atunbo tan re LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan |
9. | EDE – Awe gbolohun ede Yoruba:
i. Oriki ati alaye kikun lori awe gbolohun ii. Orisi awe gbolohun iii. Olori awe gbolohun iv. Awe gbolohun afarehen ASA – Igbagbo ati ero Yoruba nipa Ajinde leyin iku LITIRESO – Awon eka ede Yoruba: i. Ohun ti eka ede je ii. Awon eka ede to wan i ipinle kookan |
10 | EDE – Apola ninu gbolohun ede Yoruba:
i. Apola oruko ii. Apole ise iii. Ihun apola iv. Awon isori oro ti a le ba pade labe apola oruko ati apola ise ASA – Igbagbo Yoruba nipa Olodumare: i. Tani Olodumare? ii. Awon oruko ti Yoruba fi n pe Olodumare iii. Abuda ti awon Yoruba fi n pe Olodumare LITIRESO – Kika iwe ti ijoba yan |
11 | Atunyewo lori gbogbo ise saa yii |
12&13 | Idanwo ipari saa yii |
To download Second Term SS2 Yoruba Lesson Note, scroll up and click on the “Order Now” Button!
Oladipupo Ayomide olamide –
Thank you very much edupodia I really appreciate
Edupodia –
Amen. Thank you very much for your feedback.
Tijani –
You really did wonderful work, God bless you and your team, Ede Yoruba koni parun Amin. l wish you further success. Thanks.